Frances Cress Welsing | |
---|---|
![]() Welsing receives Community Award at National Black LUV Festival on September 21, 2008 | |
Ọjọ́ìbí | Frances Luella Cress Oṣù Kẹta 18, 1935 Chicago, Illinois, U.S. |
Aláìsí | January 2, 2016 Washington, D.C., U.S. | (ọmọ ọdún 80)
Ibùgbé | Washington, D.C. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Antioch College (B.S.), Howard University (M.D.) |
Iṣẹ́ | Physician |
Gbajúmọ̀ fún | The Isis Papers: The Keys to the Colors (1991) |
Frances Cress Welsing (oruko abiso Frances Luella Cress; March 18, 1935 – January 2, 2016) je oniwosan okan ara Amerika.[1] Aroko re to ko ni odun 1970, The Cress Theory of Color-Confrontation and Racism (White Supremacy),[2] je iwe to se pataki nipa itumo iwa iseojusaju awon oyinbo.